Chief Daddy (Fíìmù Nàìjíríà)
Chief Daddy | |
---|---|
Fáìlì:Chief Daddy Poster.jpg | |
Adarí | Niyi Akinmolayan |
Olùgbékalẹ̀ | Temidayo Abudu |
Àwọn òṣèré | |
Ìyàwòrán sinimá | Muhammad Atta Ahmed |
Olóòtú | Victoria Akujobi |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | EbonyLife Films |
Olùpín | EbonyLife Films FilmOne Distributions |
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 99 minutes |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | English Yoruba |
Owó àrígbàwọlé | N387.5 million [1] |
Chief Daddy jẹ́ fíìmù apanilẹ́rìn-ín ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríàtó jáde ní ọdún 2018, tí olùdarí rẹ̀ sì jẹ́ Niyi Akinmolayan, tí Bode Asianbi sì ṣe àkọsílẹ̀ rẹ̀, tí Mosunmola Abudu àti Temidayo Abudu sì ṣàgbéjáde, ní oṣù kejìlá, ọdún 2018.[2][3] Ọ̀pọ̀ àwọn ògbóǹtarìgì òṣèré bí i Funke Akindele Bello, Kate Henshaw, Nkem Owoh, Joke Silva, Patience Ozokwor, Richard Mofe Damijo àti Racheal Oniga ló kópa nínú rẹ̀.[4][5]
Ìsọníṣókí
àtúnṣeChief Daddy dá lórí ìtàn olóyè kan, tó lówó, tó lọ́là, tó sì ní ọ̀pọ̀ ilé-iṣẹ́, tó tún máa ń fi owó rẹ̀ ṣàánú fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìdílé, àwọn òṣìṣẹ́ rẹ̀ àti àwọn ìyáwó rè. Sàdédé ló kú tí ikú rẹ̀ sì fa wàhálà fún ìdílé rẹ̀.[6]
Àwọn akópa
àtúnṣe- Bisola Aiyeola gẹ́gẹ́ bí i Alásè Simbi
- Dakore Egbuson-Akande gẹ́gẹ́ bí i Remi Castle
- Funke Akindele gẹ́gẹ́ bí i Tinu Beecroft
- Zainab Balogun gẹ́gẹ́ bí i Ireti Beecroft
- Shafy Bello-Akinrimisi gẹ́gẹ́ bí i Nike Williams
- Chioma Omeruah gẹ́gẹ́ bí i Chuchu
- Ini Edo gẹ́gẹ́ bí i Ekanem
- Ihuoma Linda Ejiofor-Suleiman gẹ́gẹ́ bí i Justina
- Falz gẹ́gẹ́ bí i Femi Beecroft
- Mawuli Gavor gẹ́gẹ́ bí i Damilare Kofi Mensah
- Kate Henshaw gẹ́gẹ́ bí i Teni Beecroft
- Lepacious Bose gẹ́gẹ́ bí i Madam Tasty
- Richard Mofẹ́ Damijo gẹ́gẹ́ bí i Tega Castle
- M.I. Abaga gẹ́gẹ́ bí i Mr. X
- Beverly Naya gẹ́gẹ́ bí i Adaora
- Chinedu Ani gẹ́gẹ́ bí i Joro D
- Taiwo Obileye gẹ́gẹ́ bí i Chief Daddy
- Rachel Oniga gẹ́gẹ́ bí i Aunty Joke
- Beverly Osu gẹ́gẹ́ bí i Sandra Bello
- Nkem Owoh gẹ́gẹ́ bí i Shoffa Donatus
- Patience Ozokwor gẹ́gẹ́ bí i Madam Pat
- Joke Silva gẹ́gẹ́ bí i Lady Kay Beecroft
- Demi Banwo gẹ́gẹ́ bí i Mr. Barnabas
- Kayode Freeman gẹ́gẹ́ bí i Dr. Bada
- Ayo Lijadu gẹ́gẹ́ bí i Prelate Malachi
- Nicole Ofoegbu gẹ́gẹ́ bí i Dame Esther
- Uti Nwachukwu gẹ́gẹ́ bí i Dare Edwards
- Solomon Bryan gẹ́gẹ́ bí i Kasali
Ìṣàfihàn àti àgbéjáde
àtúnṣeChief Daddy jáde ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ní oṣù kejìlá ọdún 2018, àti ní Netherlands ní oṣù kẹta ọdún 2019, tipasẹ̀ Netflix.[7][8] Wọ́n ṣàfihàn àkọ́kọ́ fún fíìmù náà níí Oriental Hotel, ní ìlú Eko, pẹ̀lú àọn ògbóǹtarìgì òṣèré bí i Olu Jacobs, Joke Silva àti Richard Mofe Damijo.[9][10]
Ìgbóríyìn fún ilé-iṣé àti àwọn olùpín
àtúnṣeEbony Life Films ní ó ṣá̀gbéjáde fíìmù yìí, tí Film One Entertainment sì pin káàkiri ní Nàìjíríà àti ní Netherlands.[11]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Top 20 WA Films of 2019". Retrieved 7 January 2020.
- ↑ "Chief Daddy - EbonyLife Films". Ebonylifefilms.com. Archived from the original on 4 November 2021. Retrieved 20 May 2019.
- ↑ "Chief Daddy - Netflix". Netflix.com. Retrieved 20 May 2019.
- ↑ "Brace Yourselves! "Chief Daddy" Is Coming To Netflix". Guardian.ng. 4 March 2019. Archived from the original on 17 May 2019. Retrieved 20 May 2019.
- ↑ "Chief Daddy full movie cast (2018 Nigerian film)". YouTube. 10 December 2018. Retrieved 20 May 2019.
- ↑ "Chief Daddy could have been so much more but at least it will make you laugh a little". Pulse.ng. 10 December 2018. Retrieved 20 May 2019.
- ↑ "Chief Daddy grosses N115.7 million in the first ten days of release". Pulse.ng. 26 December 2018. Retrieved 20 May 2019.
- ↑ "EbonyLife Films' Chief Daddy Netflix release party - EbonyLife TV". Ebonylifetv.com. Archived from the original on 17 May 2019. Retrieved 20 May 2019.
- ↑ "Nigerian traditional outfits take centre-stage at ‘Chief Daddy’ premiere". Premiumtimesng.com. 3 December 2018. Retrieved 20 May 2019.
- ↑ "Chief Daddy Premiere: Nigerian Traditional Attire Outshines - NTA.ng - Breaking News, Nigeria, Africa, Worldwide". Nta.ng. Retrieved 20 May 2019.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Netflix acquires ‘Chief Daddy’ – Tribune Online – Friday Treat". Tribuneonlinemg.com. 8 March 2019. Archived from the original on 17 May 2019. Retrieved 20 May 2019.