Omo Ghetto
Omo Ghetto | |
---|---|
Adarí | Abiodun Olanrewaju |
Olùgbékalẹ̀ | Funke Akindele |
Òǹkọ̀wé | Funke Akindele |
Àwọn òṣèré | Funke Akindele Eniola Badmus Bimbo Thomas Ireti Osayemi Esther Kalejaiye Adebayo Salami Taiwo Ibikunle |
Orin | Baba Nee |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Scene One Productions |
Olùpín | Olasco Films Nig. Ltd. |
Déètì àgbéjáde | 24 October 2010 |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | Yoruba |
Omo Ghetto jẹ́ fíìmù àgbéléwò apanilẹ́rìn-ín ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó jáde ní ọdún 2010. Olùarí fíìmù náà ni Abiodun Olarenwaju, àwọn òṣèré tó sì kópa nínú fíìmù náà ni Funke Akindele, Bimbo Thomas, Ireti Osayemi, Esther Kalejaiye àti Eniola Badmus[1].
Àhunpọ̀ ìtàn
àtúnṣeFÍìmù náà dá lórí àwọn ìwà búburú lóríṣiríṣi tó wà nínú àwùjọ, èyí tó níṣe pẹ̀lú àwọn obìnrin tó ń ṣe jàgídíjàgan káàkiri. Ó ṣe àfihàn ẹbí, ìrúfin àti ìfọwọ́sowọpọ̀ àwọn arábìnrin.
Ìgbàwọlé
àtúnṣeOlusegun Michael for Modern Ghana gbé -ìtàn, àwọn òṣèré, àkọ́lé àti ìṣètumọ̀ àwọn ojúṣe nínú fíìmù náà, ó sì pè é ní fíìmù tó kún fún ìdánilárayá àti iṣàfihàn ọ̀pọ̀lọpọ̀ nǹkan[2]. Ní ọdún 2017, Azeezat Kareem fún Encomium Magazine ṣe àtòpọ̀ fíìmù Omo Ghetto gẹ́gẹ́ bí i ọ̀kan lára àwọn fíìmù méjì tó gbé Eniola Badmus wá sí ìta gbagede tó fi di gbajúmọ̀ òṣèré[3]. Legit.ng náà tún tò ó pọ̀ mọ́ ọ̀kan lára àwọn fíìmù márùn-ún tí a kò le gbàgbé, tó jẹ́ fíìmù Funke Akindele[4].
Àwọn akópa
àtúnṣe- Funke Akindele bí i Lefty àti Ayomide
- Bimbo Thomas bí i Nicky
- Eniola Badmus bí i Oyan
- Esther Kalejaiye bí i Omo Joibo
- Ireti Osayemi
- Adebayo Salami bí i Baba Onibaba
- Taiwo Ibikunle
- Peju Ogunmola
- Rachel Oniga
- Taiwo Hassan bí i DPO
- Yinka Quadri
- Ronke Ojo
- Lanre Oropo bí i Amofin
Ìṣàgbéjáde
àtúnṣeÀfihàn àkọ́kọ́ fún fíìmù náà wáyé ní Exhibition Hall, ní National Arts Theatre, Iganmu ní oṣùOctober, ọjọ́ 24, Ọdún 2010[5].
Apá kejì fíìmù náà
àtúnṣeOmo Ghetto: The Saga ni apá kejì fíìmù yìí, ó sì jáde ní ọjọ́ 25 oṣù December, ọdún 2020[6][7].
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Okogene, Charles (2011-01-15). "Nigeria: Omo Getto - Another Funke Akindele Story of 'Wayward Girls'". allAfrica. Retrieved 2020-10-03.
- ↑ Fafore, Olusegun Michael (2011-01-17). "Appraisal of Funke Akindele’s Omo Ghetto". Modern Ghana. Retrieved 2020-10-03.
- ↑ Azeezat, Kareem (2017-09-08). "2 movies that catapulted Eniola Badmus to fame". Retrieved 2020-10-03.
- ↑ Alawode, Abisola. "Which of these 4 roles are Funke Akindele’s most memorable?". Archived from the original on 2020-10-22. Retrieved 2020-10-03.
- ↑ "Akindele goes to the Ghetto". Vanguard (Nigeria). 2010-10-15. Retrieved 2020-10-03.
- ↑ Augoye, Jayne (2020-09-08). "Nigeria: Behind-Scene Photos From Funke Akindele's Omo Ghetto 2". allAfrica.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-12-31.
- ↑ "Behind-scene photos from Funke Akindele’s Omo Ghetto 2" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-09-07. Retrieved 2020-12-31.