Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́
Matthew Àrẹ̀mú Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́ GCFR[1] (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ karùn-ún oṣù kẹta ọdún 1937) jẹ́ gbajúmọ̀ àgbà olóṣèlú, ajagun-fẹ̀yíntí àti Ààrẹ àná orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Orúkọ bàbá rẹ̀ ni Amos Àdìgún Ọbalúayésanjọ́ "Obasanjo" Bánkọ́lé, ìyá rẹ̀ sìn ń jẹ́ Àṣàbí.Ọbásanjọ́ jẹ́ ọmọ bíbí Òwu ní ìlú Abẹ́òkúta ní ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ìyá rẹ̀ kú ní ọdún 1958, bàbá rẹ̀ sìn kú bákan náà ní ọdún 1959.
Olusegun Obasanjo | |
---|---|
Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà 12k | |
In office 29 May, 1999 – 29 May, 2007 | |
Vice President | Atiku Abubakar |
Asíwájú | Abdulsalami Abubakar |
Arọ́pò | Umaru Yar'Adua |
5th Olori Orile-ede Naijiria | |
In office February 13, 1976 – October 1, 1979 | |
Vice President | Shehu Musa Yar'Adua |
Asíwájú | Murtala Mohammed |
Arọ́pò | Shehu Shagari |
3rd Vice President of Nigeria | |
In office July 29, 1975 – February 13, 1976 | |
Ààrẹ | Murtala Mohammed |
Asíwájú | J.E.A. Wey |
Arọ́pò | Shehu Musa Yar'Adua |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 5 Oṣù Kẹta 1937 Abeokuta, Ipinle Ogun, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Lynda Obasanjo (ex-wife, aláìsí), Stella Obasanjo (aláìsí) |
Ìgbà èwe rẹ̀
àtúnṣeWọn bi Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́ ni Ojo Kaarun, Oṣù Kẹta, ọdun mẹtadinlojilẹdẹgbẹwa (1937) fún Amos Obaluayesanjo Bankole ati Asabi lilu Ìbògùn Ọláogun. O jẹ akọbi awọ̀n obi re, wọn bi ọmọ mẹjọ tẹle, ṣugbon arabirin kan loni ti ò kù. O di omo orukan nigba ti o pe omodun mejilelogun. Ile iwe Saint David Ebenezer School ni Ibogun ni oloye obasanjo ti ka iwa alakobere( primary school education),ni odun 1948. Oloye Obasanjo jé ògágun tó tifèyìntì kúrò nínú iṣẹ́ Ológun ilè Nàìjíríà ati olóṣèlú ọmọ ilè Naijiria. Oun ni Ààre ilè Naijiria lati odún 1999 títí dé ọdún 2007. Èyí ni ìgbà iketa tí Obasanjo yíò jé Ààre orílè-èdè Nàìjírìa. O ti koko je Aare laye Igba ijoba ologun laarin odun 1976 sí 1979.[2][3]
Ìfẹ̀yìntì rẹ̀
àtúnṣeLẹ́yìn tí ó fẹ̀yìntì, ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ àdáṣe tirẹ̀, ìyẹn ní iṣẹ́ àgbẹ̀. Ilé-iṣẹ́ àgbẹ̀ rẹ̀, (Obasanjo Farms) gbòòrò; tó fẹ́rẹ ma sí abala iṣé àgbẹ̀ tí kò sí níbẹ̀. Láàrín ọdún 1976 sí 1999, Obasanjo di ẹni mímọ̀ ní gbogbo àgbáyé. Akinkanju ni ninu eto oselu agbaye. O wa ninu awon Igbimo to n petu si aawo ni awon orile-ede to n jagun, paapaa ni ile adulawo. O je ogunna gbongbo ninu egbe kan to koriira iwa ibaje, iyen ni Transparency International. Ni odun 1999, Obasanjo tun di Aare alagbada fun orile-ede Naijiria, labe asia egbe PDP. A tun fi ibo yan an pada gege bi Aare lekeji ni 2003..[4] Okan pataki ninu awon afojusun ijoba Obasanjo ni igbogun ti iwa jegudujera (Anti-Corruption). Obasanjo gbiyanju dida ogo Naijiria pada laarin awon akegbe re ni agbaye (Committee of nations). O tun iyi owo naira to ti di aburunmu bi omi gaari se, gbigbowo-lori-oja (inflation) si dinku jojo. Iye owo afipamo-soke-okun (external reserves) Naijiria ti ga gan-an ni, o to $40 billion bayii. Obasanjo tun fidi awon banki wa mule gbogbo, pipo ti won po yanturu tele ti dinku, won o ju meeedogbon lo mo bayii. Eyi mu ki awon eniyan ni igbekele ninu fifi owo pamo si banki, won si tun le ya owo fun idagbasoke okowo won gbogbo. Lara awon eto ti ijoba Obasanjo n se ni tita awon ogun ijoba fun awon aladani (privatisation policy). Eto yii ku die kaato. Idi ni pe awon olowo lo le ra awon ogun bee, talika kankan ko le ra won.
Ni Oṣu Kẹjọ ọdun 2021, Ẹgbẹ Afirika yan Olusegun Obasanjo gẹgẹbi Aṣoju giga fun Alaafia ni Iwo Afirika.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Statement by Obasanjo to the United Nations" (PDF). Retrieved 2011-04-23.
- ↑ "Olusegun Obasanjo". Encyclopaedia Britannica. 21 May 2014. http://global.britannica.com/EBchecked/topic/423633/Olusegun-Obasanjo. Retrieved 23 February 2015.
- ↑ "President of Nigeria loses bid for a 3rd term". International Herald Tribune. 29 March 2009. Retrieved 2011-04-23.
- ↑ "Annual Abstract of Statistics, 2012". National Bureau of Statistics. National Bureau of Statistics. pp. 595–596. Archived from the original (PDF) on 28 January 2015. Retrieved 3 April 2015.
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Olusegun Obasanjo |
Àwọn àjápọ̀ látìta
àtúnṣePreceded by Murtala Mohammed |
Head of the Federal Military Government of Nigeria 13 February 1976– 1 October 1979 |
Succeeded by Shehu Shagari |
Preceded by None |
Peoples Democratic Party (PDP) Presidential Nominee 1999 (won), 2003 (won) |
Succeeded by Umaru Yar'Adua |
Preceded by Abdulsalami Abubakar as Chairman of the Provisional Ruling Council of Nigeria |
President of Nigeria 29 May 1999 – 29 May 2007 |
Succeeded by Umaru Yar'Adua |
Preceded by John Howard |
Commonwealth Chairperson-in-Office 2003–2005 |
Succeeded by Lawrence Gonzi |
Preceded by Joaquim Chissano |
Chairperson of the African Union 2004–2006 |
Succeeded by Denis Sassou-Nguesso |
Cabinet of President Olusegun Obasanjo 1999-2003 | |||||||||||||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Atiku Abubakar (1999-2007) | |||||||||||||||||||||||
Agriculture | |||||||||||||||||||||||
Aviation | Olusegun Agagu (May 1999-February 2001) • Kema Chikwe (February 2001-May 2003) | ||||||||||||||||||||||
Commerce | Mustapha Bello (June 1999 - 2002) • Precious Ngelale (- May 2003) | ||||||||||||||||||||||
Communications | Mohammed Arzika (June 1999 - June 2001) • Haliru Mohammed Bello • (June 2001 - May 2003) | ||||||||||||||||||||||
Co-operation and Integration in Africa | Jerry Gana (May 1999 -) | ||||||||||||||||||||||
Theophilus Danjuma (Jun 1999-2003) | |||||||||||||||||||||||
Education | Tunde Adeniran (June 1999 - February 2001) • Babalola Borishade (February 2001 - ) | ||||||||||||||||||||||
Environment (Later + Housing) | Hassan Adamu (Jun 1999 - 2000) • Sani Daura (2000 - January 2001) • Mohammed Kabir Said (February 2001 -) | ||||||||||||||||||||||
FCT Administration | Ibrahim Bunu (June 1999 - February 2001) • Mohammed Abba Gana (February 2001 - ) | ||||||||||||||||||||||
Finance | Adamu Ciroma (Jun 1999–2003) | ||||||||||||||||||||||
Foreign Affairs | Sule Lamido (Jun 1999–2003) | ||||||||||||||||||||||
Health | Tim Menakaya (Jun 1999–February 2001) • ABC Nwosu (February 2001–2003) | ||||||||||||||||||||||
Industries | Iyorchia Ayu (Jun 1999 - 2000) • Stephen Akiga (2000 - January 2001) • Kolawole Babalola Jamodu (February 2001 - May 2003) | ||||||||||||||||||||||
Information and National Orientation | Dapo Sarumi (June 1999 - January 2001) • Jerry Gana (February 2001 - ) | ||||||||||||||||||||||
Internal Affairs | Sunday Afolabi (June 1999 -) • Mohammed Shata (- May 2003) | ||||||||||||||||||||||
Justice (Attorney General) | |||||||||||||||||||||||
|
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Olusegun Obasanjo |