Stella Oduah-Ogiemwonyi

Stella Oduah Ogiemwonyi tí a bí ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kinni ọdún 1962(5 January 1962) jé òkan lára àwon asofin agba(Senato) Nàìjirià àti Minisita Ofurufu tẹ́lẹ̀rí.[3] O bura wolé sí ipò minisita ofurufu ni ojó keji, Oṣu Keje, Ọdun 2011(July 2, 2011), [4] Ṣugbọn a yọọ kuroní ipo náà ní ọjọ kejila Oṣu Keji ọdun 2014(12 February, 2014). [5] O tunbá ááre teleri Goodluck Jonathan se ipolongo nigba ipolongo oṣelú rè fún ààre orílè-èdè Nàìjíríà.

Stella Oduah
Senator of the Federal Republic of Nigeria from Anambra North Senatorial District
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
June 2015
ConstituencyAnambra North
Federal Minister of Aviation, Nigeria
In office
4 July 2011 – 12 February 2014
AsíwájúFidelia Njeze
Arọ́pòMr. Osita Chidoka
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí5 Oṣù Kínní 1962 (1962-01-05) (ọmọ ọdún 62)
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeoples Democratic Party (PDP)
Àwọn ọmọMaxwell Chinedu Toritseju Etoromi[1] Tuoyo Etoromi Oduah[2]

Ní ọdún 2013, òun, Viola Onwuliri àti David Mark jé okan lára awon tí Ààrẹ yàn láti lọ síbi ìfisípò Póòpù ti Póòpù Francis. [6] Ni ọjọ 23 February 2017, Iwe iroyin Punch se atejade nipa bí awọn ile-iṣẹ mẹrin rẹ se duro nitori ẹsun gbese $ 16,412,819.06 ati N100,493,225.59 tí ile-ẹjọ giga ti Ijoba ni Eko se fikan. Awọn ile-iṣẹ mẹrin naa ni: Sea Petroleum and Gas Company Limited, Sea Shipping Agency Limited, Rotary Engineering Services Limited, ati Tour Afrique Company Limited pẹlu awọn akọọlẹ banki mokanlelogun. Orisirisi èsùn ni a ti fikan, àwon èsùn bi rira oko ayokele BMW meji láì gba ona tótọ́. [7]

Ni odun 2015, a yan sipo gegebi asofin agba(Senator) láti se asoju ariwa Anambra,[8] èyí tí ó mú kí ówà lara àwon obinrin meje tí ayàn sí ipò asofin agba kejo ní odun 2015, àwon toku tí ójé ni Rose Okoji Oko, Uche Ekwunife, Fatimat Raji Rasaki, Oluremi Tinubu, Abiodun Olujimi ati Binta Garba. Atun dìbòyàn sí ipò náà ní odun 2019. [9] Ní August 26, 2021, Stella Oduah fi egbe oselu People's Democratic Party(PDP) sile lati darapo mó egbe All Progressive Congress(APC).[10] Ìkọ kedere

Ìpìlè

àtúnṣe

A bí Oduah si inu idile Igwe D.O. Oduah ti ìlú Akili-Ozizor, Ogbaru L.G.A, Ìpínlẹ̀ Anambra ní ọjọ́ 5 January 1962. Oduah-Ogiemwonyi gba òyè Bachelors ati Oye Masters (ninu Iṣiro ati Iṣakoso Iṣowo) ni Orílè-èdè Amẹrira kí o tó padà sí Nàìjíríà ní ọdún 1981, ó sì dara pọ̀ mọ́ ilé-iṣẹ́ Epo ilẹ̀ Nàìjíríà tí à mò sí Nigerian National petroleum cooperation(NNPC)

Ni ọdun 1992, o kuro ni NNPC lati dá ilé ise Sea Petroleum & Gas Company Limited (SPG) sile, ilé-isé náà ún ta àwon nkan abajade epo Petroleum ni Nigeria. Oduah fé Engr. Chris Ogiemwonyi, minisita télèrí fun iṣẹ, wón sì bí àwon omo.

Otún le ka èyí

àtúnṣe

Rose Okoji Oko

Aishatu Dahiru Ahmed

Uche Ekwunife

Betty Apiafi

Akon Eyakenyi

Wendy Okolo

Yemisi Edun

Patricia Etteh

Kafayat Oluwatosin(Kaffy)

Joan Onyemaechi Mrakpor

Bamidele Abiodun

Elizabeth Adekogbe

Mulikat Adeola Akande

Halima Tayo

Simi Johnson

Folorunsho Alakija

Adefunmilayo Tejuosho

Àwon Ìtókasí

àtúnṣe
  1. http://saharareporters.com/2016/08/31/father-tells-stella-oduah-return-late-son%E2%80%99s-body-proper-burial
  2. "Stella Oduah's ex-spouse raises concern over child's safety". 6 September 2016. 
  3. "Former aviation minister Stella Oduah for arraignment November 22 - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. 2021-10-20. Archived from the original on 2022-05-19. Retrieved 2022-05-19. 
  4. "Senate President David Mark Read The List of Nigeria's Ministerial Nominees". InfoStride News. 2011-06-29. Retrieved 2022-05-19. 
  5. Emmanuel, Ogala (2014-02-12). "BREAKING: Jonathan drops corrupt Aviation Minister, Stella Oduah, 3 others". Premium Times Nigeria. Retrieved 2022-05-19. 
  6. "Pope Inauguration: David Mark To Lead FG Delegation To Vatican City". Information Nigeria. 2013-03-15. Retrieved 2022-05-19. 
  7. "How Aviation Minister Stella Oduah Forced Cash-Strapped Aviation Agency To Spend $1.6 Million On Two BMW Armored Cars For Her". Sahara Reporters. 2013-10-15. Retrieved 2022-05-19. 
  8. Olowolagba, Fikayo (2019-02-25). "Nigeria election result: PDP's Stella Oduah wins Anambra North senatorial seat". Daily Post Nigeria. Retrieved 2022-05-19. 
  9. Oyewobi, Akin (2019-02-25). "Stella Oduah wins Anambra North Senatorial Election". Premium Times Nigeria. Retrieved 2022-05-19. 
  10. Shibayan, Dyepkazah (2021-08-26). "Stella Oduah dumps PDP for APC". TheCable. Retrieved 2022-05-19.