Wikipedia:Àwùjọ Àwọn tí ó nífẹ sí Nàìjíríà


[[Category:Active WikiProjects|Àdàkọ:WikiProjectbasename]]

Àdàkọ:Infobox WikiProject

Ẹkáàbọ̀ sí Àwùjọ Àwọn tí ó nífẹ sí àpilẹ̀kọ nípa ilẹ̀ Nàìjíríà ! Iṣẹ́ àkànṣe yí ni a gbà lérò láti fẹ̀ , ṣàtúntò, túnṣe, kí á sì túbọ̀ kọ nípa àwọn átíkù tó nííṣe pẹ̀lú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láì fepo-bọyọ̀ rárá. A àgbà wípé iṣẹ́ àkànṣe yí yóò ran àwọn olùkọ́ Wikipedia tó kú lọ́wọ́ láti mọ ibi tí Iṣuẹ́ tún kù sí láti ṣe. Bóyá ẹ nífẹ̀ẹ́ l àti ran wá lọ́wọ́ lórí ohun-kóhun, ẹ jọ̀wọ́ ẹ fi ìbéèrè yín sí ojú ewé Ìbánisọ̀rọ̀ wa.

Àníyàn wa

àtúnṣe

Àwùjọ yí ni ó rànbwá lọ́wọ́ láti ṣe àmójútó akitiyan bí a ṣe ń mú ìdàgbàsókè, ṣíṣàtúńṣe àti àbójútó àwọn àpilẹ̀kọ tó níṣe pẹ̀lú orílẹ̀-èdè:

Àfojúsùn wa

àtúnṣe

Àfojúsùn wa pín sí ọ̀nà méj:

  • Àfojúsùn gbogbo gbo: èyí ni àfojúsùn nípa kíkọ àwọn átíkù (àpilẹ̀kọ) tí ó níṣe pẹ̀lú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lápapọ̀.
  • Àfojúsùn pàtàkì/gbọ̀ọ́n: èyí ni láti kọ nípa àṣàyàn àpilẹ̀ (átíkù) kan tàbí ọ̀pọ̀. Àwọn àfojúsùn méjèèjì òkè yí ni ẹnikẹ́ni le ṣe àtúnṣe sí nígbà tí a bá ti jíròrò lórí wọn ní pèpéle Ìjíròrò wa.

Àwọn ohun tí a fẹ́

àtúnṣe
  1. Láti ri wípé gbogbo àwọn apilẹ̀kọ tí ó jẹ mọ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà wà ní that "àláfíà", sẹpẹ́ àti ní dédé.
  2. Kí a dẹ́kun tàbí mú àdínkù bá and accurate, minimising ìbaṣẹ́jẹ́ àti la lo àwọn ìkànì tí kò tọ́ bí ó ti wulẹ̀ kí ó mọ. Àwọn ìpènija tí a mẹ́nu bá yí ni ó jẹ́ ohun tí ó wọ́pọ̀ nínú àwọn àpilẹ̀kọ tí ó níṣe pẹ̀lú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ìdí nìyí tí a fi mu ní ọ̀kúnkúndùn. Lára àwọn àfojúsùn wa náà ni:
  3. Dídá à wọn átíkù tí ó peregedé tí ó sì fi òtítọ́ ìtàn àti àṣà àwọn ọmọ orílẹ́-èdè Nàìjíríà hànde.
  4. Fífi ìbásepọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti àwọn orílẹ̀-èdè míràn nípa àṣà òun ìṣe hàn sí gbogbo àgbáyé.
  5. Kí á fẹsẹ̀ àwọn àpilẹ̀kọ tí ó rọ̀ mọ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà múlẹ̀ ṣinṣin, kí wọ́n sì wà ní ààtò tí ó tọ́.
  6. Kí á ṣe àfikún gbogbo ìròyìn pàá pàá jùlọ èyí tí ó tọ́ nípa àwọn obìnrin, àwọn aláìní tí wọ́n jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà hànde . Ẹ̀wẹ̀, àwọn ìró yí gbọdọ̀ ní ìtọ́kasí, ó w á kéré tán ìtàkùn ìjásóde tí ó lè fìdí ìròyìn, ìró tàbí ìṣẹ̀lẹ̀ nípa àwọn àpilẹ̀kọ wa gbogbo múlẹ̀.
  7. Kí á fẹsẹ̀ òfin, ìlànà, àti ìlò èdè abínibí múlẹ̀ nínú ìṣògbufọ̀ àti àpilẹ̀kọ ní gbogbo ọ̀nà. Ní

Àwọn Àfojúsùn pàtàkì

àtúnṣe

Bí ó bá wù wá, a lè dá àfojúsùn pàtàkì yí sílẹ̀ tàbí kí a paárẹ́ ìfilọ̀, èyí lè wáyé látàrí bí àwọn olùkópa bá ṣe ń kópa sí nínú iṣẹ́ àkànṣe náà. Àwọn àfojúsùn ní a ní láti ṣàgbéyẹ̀wò kí á sì ṣàfíkún wọn lẹ́yìn tí a bá jíròrò lórí wọn tan. Ilẹ̀kùn ṣá sílẹ̀ fún ẹnìkẹ́ni láti bá àbá wá kí á sì jọ ṣàgbéyẹ̀wò rẹ̀ órí pèpéle Ìjíròrò wa. Àfojúsùn wa pàtàkì jùlọ ni:

  • Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bí átíkù; átíkù yí ni púpọ̀ nínú tí wọn kò forúkọ wọn sílẹ̀ tàbí àwọn oníṣẹ́ titun ma ń bàjẹ́ẹ́ lọ́pọ̀ ìgbà nípa fífi ìtàkùn ìjálura tí kò tọ́ sànẹ̀, tàbí kí wọ́n ṣe ìròyìn ẹlẹ́jẹ̀ (tí kìí ṣòótọ́) kún àpilẹ̀kọ yí. Fúndí èyí, a ní láti ma ṣọ́ átíkù yí ní gbogbo ìgbà kí á sì ma ṣàtúnṣe rẹ̀ kí á lè dẹ́kun ìwà ìbàjẹ́ náà. Ọ̀pọ̀ ìkọminú ni àwọn alábàáṣe wa nílẹ̀ òkèrè ti mú wá lórí bí ìbàjẹ́ ṣe ń wáyé lórí átíkù yí, pàá pàá jùlọ nípa ṣíṣe ìyapa ẹnu lórí pàtó iye ènìyàn tí wà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nínú ètò ìkàniyàn olori-ò-jorí tí ó ti wáyé nílẹ̀ Nàìjíríà, (bóyá kí á sì dá átíkù sílẹ̀ fún ètò ìkàniyàn lọ́tọ̀?). Kò tan síbẹ̀, Bákan náà ni èyí rí pẹ̀lú àwọn ìlú ńlá ńlá ẹ̀sìn ìbílẹ̀ àwọn ìran ìran ni kò bójú mu tó.
  • Ìtàn ilẹ̀ Nàìjíríà; àti àwọn tí awọn èyíbtí a ti sọ tẹ́lẹ̀ pẹ́lú àwọn tí afẹ́ mẹ́nu bà nísàlẹ̀ yí ni wọ́n jẹ́ ohun tí ó ńbtini lójú jọjọ.
  • Àpilẹ̀kọ nípa Àtíkù Abubakar; ni ihà tí kálukú oníṣẹ́ Wikipedia kọ sí ìṣèlú pàá pàá jùlọ ọ̀gbẹ́ni náà ti ba àpilẹ̀kọ nípa arákùnrinnnáàbjẹ́ púpọ.
  • Àpilẹ̀kọ nípa Lucky Igbinedion; ni kò láàáfíà rárá tí kò sì dàgbà sókè fún ọdún pípaẹ́.

Àwọn iṣẹ́ mìíràn tí a tún ní lọ́kàn

àtúnṣe
  • Bí ó ṣe jẹ́ wípé àwọn àpilẹ̀kọ tí ó jẹ mọ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni kò sí nínú àtò, èyí ó lè mú kí rí àtúnṣe. Bí a bá fi wọ́n sínú ààtò tí ó yẹ, ó dájú wípé wọn yóò tètè rí àtúnṣe tí ó tọ́.
  • Olè fi Abala:Àkànṣe Wiki Nàìjíríà sí pèpéle ìbánisọ̀rọ̀ nípa àwọn àpilẹ̀kọ/átíkù tó jẹ mọ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kí wọ́n lè mọ̀ọ́ bẹ́ẹ̀.

Àwọn átíkù tí a fẹ́ kí ẹ bá wa kọ nìwọ̀nyí

àtúnṣe

Àwọn átíkù tí wọ́n fẹ́ àtúnṣe

àtúnṣe

Àwọn olùkópa

àtúnṣe
Ó wù wá kí a ní àwọn olùkópa bíi ti èrò ọjà yí.

Àwọn Oníṣẹ́ àtìgbà-dégbà

àtúnṣe

Láti kópa nínú àwọn iṣẹ́ àkànṣe Wiki Nàìjíríà yí, ẹ ṣe àtúnkọ ojú ewé yí kí ẹ sì ṣàfikún wọ̀nyí: Wikitext #{{subst:me}}. Ẹ ṣe àkọsílẹ̀ abala tí ó wù yín láti máa kópa lábẹ́ àtòjọ orúkọ àwọn Oníṣẹ́. Àwọn olùkópa tún ní láti fi Orúkọ ìdánimọ̀ Oníṣẹ́ wọn síbẹ̀.  page. Ẹ lè wo àpẹẹrẹ ìtàkùn yí clicking here kí ẹ lè fi sí abẹ́ ìṣọ́ yín.

  1. T Cells (talk⧼dot-separator⧽contribs)
  2. Agbalagba (talk⧼dot-separator⧽contribs)

Àmì ìdánimọ̀ àwọn Olùkópa

àtúnṣe

Àwọn olùkópa nínú iṣẹ́ àkànṣe Wiki Nàìjíríà ní láti ṣe àfikún àwọn Ìlà yí Wikitext sí ojú ewé wọ. Láti ṣe èyí, ẹ lo ìlànà yí user page Àdàkọ:Nobreak. Àdàkọ:Yytop Àdàkọ:Yycat Àdàkọ:Yy Àdàkọ:Yy Àdàkọ:Yy Àdàkọ:Yyend For other Nigeria user templates, see Àdàkọ:Nobreak.

BLPs
Àwọn orin
Àwọn mìíràn ni

Àwọn ohun èlò

àtúnṣe

Ìgbéléwọ̀n

àtúnṣe

Wikipedia:Version

Àwọn Gbàgede

àtúnṣe

Gbàgede àwọn Átíkù gbogbo gbò:


Fún àwọn átíkù tí wọ́n dá wà (stub)s, nínú àwọn àpilẹ̀kọ tí a ti mẹ́nu bà tí wọ́n sì nílò kí a fẹ̀ wọ́n lójú síwájú si, ẹ fi ọ̀kan nínú àwọn ìtàkùn yí sí irúfẹ́ átíkù bẹ́ẹ̀ lábẹ́.

Ẹ lè lo ìlànà ìbánisọ̀rọ̀ fún ojú-ewé àwọn átíkù *{{Iṣẹ́ àkànṣe Wikipedia Yorùbá}}

Bí ẹ bá fẹ́ bá àwọn oníṣẹ́ tí wọ́n nífẹ̀ẹ́ sí iṣẹ́ àkànṣe Wikipedia Yiruba, ẹ kàn sí wọn lórí: {{Oníṣẹ́ Iṣẹ́ Àkànṣe Wikipedia Yorùbá}}, ìyẹn tí ẹ bá jẹ́ ọ̀kan lára wọn. Àmọ́ tí ẹ bá jẹ́bọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ẹ lè lo ìtàkùn yí láti fi kan sí wọn

Àwọn Ìpínsísọ̀rí

àtúnṣe

Àwọn ojú-èwe mìíràn

àtúnṣe

Átíkù ìfitónilétí

àtúnṣe

Àdàkọ:Àwọn tábìlì Átíkù ìfitónilétí

Átíkù tó ń hooru

àtúnṣe

Àwọn ojú-ewé tí ó gbajúmọ̀

àtúnṣe

Ojú-ewé tí ṣí kà jùlọ ní a lè rí ní orí ìtàkùn yí Wikipedia:WikiProject Nigeria/Ojú-ewé tó gbajúmọ̀ (tí a ń ṣe kòkárí rẹ̀ lóṣooṣù).

Àwọn iṣẹ́ àkànṣe ti Wikipedia tó kù

àtúnṣe

Commons and Wikinews

àtúnṣe
What to type What it makes
{{Commons|Nigeria}}
{{Commons category|Nigeria}}


{{Wikinews|Nigeria}}
Wikinews ní ìròhìn lórí ọ̀rọ̀ yíì:
{{Wikinewscat|Nigeria}} Àdàkọ:Wikinewscat

Wikipedias in Nigerian languages

àtúnṣe
What to type What it makes
{{InterWiki|code=ff|Fulfulde}} Àdàkọ:InterWiki
{{InterWiki|code=ha|Hausa}} Àdàkọ:InterWiki
{{InterWiki|code=ig|Igbo}} Àdàkọ:InterWiki

Ààtò àwọn olùṣàtúnṣe

àtúnṣe

Oníṣe:WolterBot/ ìdarapọ̀ mọ́ àwọn olùṣàtúnṣe

Àwọn ojú-ewé tó farajọra

àtúnṣe

Àdàkọ:Africa-related WikiProjects

Ẹ wo: Wikipedia:Irinṣẹ́

Àdàkọ:Help navigation Àdàkọ:Wikipedia policies and guidelines Àdàkọ:WikiProject Footer