Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Oṣù Kejì
- 1924 – The United Kingdom recognizes the USSR.
- 1958 – Egypt and Syria merge to form the United Arab Republic, which lasted until 1961.
- 1982 – Senegal and the Gambia form a loose confederation known as Senegambia.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1834 – Henry McNeal Turner, bísọ́ọ̀bù ará Amẹ́ríkà (al. 1915)
- 1902 – Langston Hughes (fọ́tò), olùkọ̀wé ará Amẹ́ríkà (al.1967)
- 1906 – Adetokunbo Ademola, Olùdájọ́ Àgbà Nàìjíríà (al. 1993)
- 1931 – Boris Yeltsin, Ààrẹ ilẹ̀ Ìparapọ̀ Rọ́síà 1k (al. 2007)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1958 – Clinton Davisson, American physicist, Nobel Prize Laureate (ib. 1888)
- 1970 – Alfréd Rényi, Hungarian mathematician (ib. 1921)
- 1976 – Werner Heisenberg, German physicist, Nobel Prize Laureate (ib. 1901)
- 1971 – Idi Amin replaces President Milton Obote as leader of Uganda.
- [[]]
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1882 – James Joyce (fọ́tò), olùkọ̀wé ará Írẹ́lándì (al. 1941)
- 1905 – Ayn Rand, Russian-born American author and philosopher (d. 1982)
- 1926 – Valéry Giscard d'Estaing, French politician
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1907 – Dmitri Mendeleev, Russian chemist (b. 1834)
- 1970 – Bertrand Russell, English philosopher, Nobel laureate (b. 1872)
- 1974 – Imre Lakatos, Hungarian philosopher (b. 1922)
3 Oṣù Kejì {{Àjọ̀dún |data= Ọjọ́ 3 Oṣù Kejì |àwòrán= |ìjúwe= |ìṣẹ̀lẹ̀=
- [[]]
- [[]]
|ìbí=
- 1948 – Carlos Felipe Ximenes Belo, East Timorese politician, Nobel Peace laureate
- [[]]
|aláìsí=
- 1922 – John Butler Yeats, Northern Irish artist (b. 1839)
- 1924 – Woodrow Wilson, 28th President of the United States, Nobel laureate (b. 1856)
- 1789 – George Washington jẹ́ dídíbòyàn láìlólódì bíi Ààrẹ àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà àkọ́kọ́ látọwọ́ Ẹgbẹ́ Oníbò Amẹ́ríkà.
- 1794 – Ilé Aṣòfin Fránsì f'òfin pa oko-erú rẹ́ káàkiri agbègbè Orílẹ̀-èdè Fránsì.
- 1859 – Ìwé Codex Sinaiticus jẹ́ wíwárí ní Egypt.
- 1969 – Yasser Arafat di alága PLO.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1913 – Rosa Parks (fọ́tò), alákitiyan ẹ̀tọ́ aráàlú ará Amẹ́ríkà (al. 2005)
- 1725 – Dru Drury, aṣeọ̀rọ̀kòkòrò ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì (al. 1804)
- 1947 – Dan Quayle, Igbákejì Ààrẹ àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà 44k.
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1928 – Hendrik Lorentz, aṣefísíksì ará Hóllándì àti ẹlẹ́bùn Nobel (ib. 1853)
- 2001 – J. J. Johnson, olórin jazz ará Amẹ́ríkà (ib. 1924)
- 2005 – Ossie Davis, Òṣeré àti alákitiyan ará Amẹ́ríkà (ib. 1917)
- 1885 – Ọba Leopold 2k ilẹ̀ Bẹ́ljíọ̀m sọ Kóngò di ohun àdáni rẹ̀.
- 1958 – Gamel Abdel Nasser (fọ́tò) jẹ́ dídálórúkọ láti di ààrẹ àkọ́kọ́ Orílẹ̀òmìnira Árábù Aparapọ̀.
- 1962 – Ààrẹ Fránsì Charles De Gaulle gbà pé kí Algeria di alómìnira.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1914 – Alan Lloyd Hodgkin, ẹlẹ́bùn Nobel (al. 1998)
- 1915 – Robert Hofstadter, ẹlẹ́bùn Nobel (al. 1990)
- 1919 – Andreas Papandreou, olóṣèlú ọmọ Grííkì (al. 1996)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1790 – William Cullen, aṣekẹ́místrì ará Skọ́tlándì (ib. 1710)
- 1881 – Thomas Carlyle, olùkọ̀wé ará Skọ́tlándì (ib. 1795)
- 2005 – Gnassingbe Eyadema, Ààrẹ ilẹ̀ Tógò (ib. 1937)
- 1820 – Àwọn akórawọ̀lú ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà 86 àkọ́kọ́ tí Ẹgbẹ́ Ìsọdàmúsìn Amẹ́ríkà ṣonígbọ̀wọ́ bẹ̀rẹ̀ ìtẹ̀dó ní ibi tí Liberia wà lóòní.
- 1942 – Ogun Àgbáyé 2k: Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan gbógun ti Thailand.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1911 – Ronald Reagan, Ààrẹ 40k Àwọn Ìpínlẹ̀ Aparapọ̀ (al. 2004)
- 1945 – Bob Marley (fọ́tò), olórin ará Jamáíkà (al. 1981)
- 1950 – Natalie Cole, olórin ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1916 – Rubén Darío, olùkọ̀wé ará Nicaragua (ib. 1867)
- 1964 – Emilio Aguinaldo, Ọgágun àti Ààrẹ ará Filipínì (ib. 1869)
- 1993 – Arthur Ashe, agbá tẹnís ará Amẹ́ríkà (ib. 1943)
Ọjọ́ 7 Oṣù Kejì: Ọjọ́ Ìlómìnira ní Grenada (1974)
- 1962 – Orílẹ̀-èdè Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà fòfinde gbogbo ọjà sí àti láti Kúbà.
- 1979 – Pluto bọ́ sínú ọ̀nàìyípò Neptune fún ìgbà àkọ́kọ́ látìgbà tí àwọn méjèjì jẹ́ wíwárí.
- 1986 – Ìjọba ọdún méjìdínlọ́gbọ̀n Ààrẹ Jean-Claude Duvalier wásópin ní Haiti, nígbà tó sákúrò níbẹ̀.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1812 – Charles Dickens, olùkọ̀wé ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì (al. 1870)
- 1885 – Sinclair Lewis, ẹlẹ́bùn Nobel ará Amẹ́ríkà (al. 1951)
- 1965 – Chris Rock (fọ́tò), aláwàdà àti òṣeré ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1937 – Elihu Root, ẹlẹ́bùn Nobel ará Amẹ́ríkà (ib. 1845)
- 1964 – Sophoklis Venizelos, olóṣẹ̀lú ọmọ Grííkì (ib. 1894)
- 1986 – Cheikh Anta Diop, akọìtàn ará Senegal (ib. 1923)
- 1974 – Ìfipágbàjọba ológun ní Upper Volta.
- 1979 – Denis Sassou-Nguesso di Ààrẹ Orílẹ̀olómìnira ilẹ̀ Kóngò fún ìgbà àkọ́kọ́.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1612 – Samuel Butler, akọewì ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì (al. 1680)
- 1700 – Daniel Bernoulli, onímathimátíkì ọmọ Hólàndì (al. 1782)
- 1834 – Dmitri Mendeleev (fọ́tò), aṣekẹ́místrì ará Rọ́síà (al. 1907)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1921 – Peter Kropotkin, amòye ará Rọ́síà (ib. 1842)
- 1999 – Iris Murdoch, olùkòwé ará Írẹ́lándì (ib. 1919)
- 1957 – John von Neumann, aṣefísíksì àti onímathimátíkì ọmọ Húngárì (ib. 1903)
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1737 – Thomas Paine, Amòye ará Amẹ́ríkà (al. 1809)
- 1940 – J. M. Coetzee, olùkọ̀wé ará Gúúsù Áfríkà
- 1943 – Joseph E. Stiglitz, aṣeọ̀rọ̀-òkòwò ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1881 – Fyodor Dostoyevsky (àwòrán), olùkọ̀wé ará Rọ́síà (ib. 1821)
- 1906 – Paul Laurence Dunbar, olùkọ̀wé ará Amẹ́ríkà (al. 1872)
- 1994 – Howard Martin Temin, ẹlẹ́bùn Nobel ará Amẹ́ríkà (ib. 1934)
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1890 – Boris Pasternak, Russian writer, Nobel Prize Laureate (al. 1960)
- 1898 – Bertolt Brecht, German author (al. 1956)
- 1910 – Dominique Pire, Belgian friar, Nobel Prize Laureate (al. 1969)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1837 – Aleksandr Pushkin, Russian poet and novelist (ib. 1799)
- 1923 – Wilhelm Röntgen, German physicist, Nobel Prize Laureate (ib. 1845)
- 1992 – Alex Haley, American author (ib. 1921)
- 2014 – Stuart Hall, omowe ara Jamaika (ib. 1932)
- 1953 – The Soviet Union breaks off diplomatic relations with Israel.
- 1990 – Nelson Mandela, a political prisoner for 27 years, is released from Victor Verster Prison outside Cape Town, South Africa.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1776 – Ioannis Kapodistrias, Greek diplomat of the Russian Empire and first head of state of independent Greece (d. 1831)
- 1900 – Hans-Georg Gadamer, German philosopher (d. 2002)
- 1934 – Manuel Noriega, Panamanian general and dictator
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1650 – René Descartes, French philosopher (b. 1596)
- 1996 – Kebby Musokotwane, Prime Minister of Zambia (b. 1946)
- 2012 – Whitney Houston (foto), akorin ara Amerika (ib. 1963)
- 1502 – Vasco da Gama sets sail from Lisbon, Portugal, on his second voyage to India.
- 1934 – The Austrian Civil War begins.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1809 – Charles Darwin, English naturalist (d. 1882)
- 1809 – Abraham Lincoln, 16th President of the United States (al. 1865)
- 1934 – Bill Russell, agbaboolu alapere ara Amerika
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1804 – Immanuel Kant, German philosopher (b. 1724)
- 1916 – Richard Dedekind, German mathematician (b. 1831)
- 1984 – Julio Cortázar, Argentine writer (b. 1914)
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1835 – Mirza Ghulam Ahmad, Founder of the Ahmadiyya Muslim Community (d. 1908)
- 1933 – Paul Biya, Cameroon politician
- 1855 – Paul Deschanel, French President (d. 1922)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1942 – Epitácio Pessoa, Brazilian president (ib. 1865)
- 1976 - Murtala Muhammad, olórí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (ib. 1938)
- 1992 – Nikolay Bogolyubov, Russian mathematician (b. 1909)
- 1961 - Lawrencium, is first synthesized at the University of California.
- 1989 – The first of 24 satellites of the Global Positioning System are placed into orbit.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1818 – Frederick Douglass (fọ́tò), American abolitionist (d. 1895)
- 1869 – Charles Wilson, Scottish physicist, Nobel Prize Laureate (d. 1959)
- 1895 – Max Horkheimer, German philosopher and sociologist (d. 1973)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1779 – James Cook, British naval captain and explorer (b. 1728)
- 1943 – David Hilbert, German mathematician (b. 1862)
- 1949 – Yusuf Salman Yusuf, Iraqi-Assyrian communist leader (b. 1901)
- 1950 – The Soviet Union and the People's Republic of China sign a mutual defense treaty.
- 2005 – YouTube, the Internet site on which videos may be shared and viewed by others, is launched in the United States.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1564 – Galileo Galilei, Italian astronomer and physicist (d. 1642)
- 1748 – Jeremy Bentham, English philosopher (d. 1832)
- 1861 – Alfred North Whitehead, English mathematician and philosopher (d. 1947)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1965 - Nat King Cole, olórin ará Amẹ́ríkà (al. 1919)
- 1988 – Richard Feynman, American physicist, Nobel Prize Laureate (b. 1918)
- 1999 – Big L, American rapper (b. 1974)
- 1959 – Fidel Castro becomes Premier of Cuba after dictator Fulgencio Batista was overthrown on January 1.
- 2005 – The Kyoto Protocol comes into force, following its ratification by Russia.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1543 – Kano Eitoku, Japanese painter (d. 1590)
- 1932 – Ahmad Tejan Kabbah, President of Sierra Leone
- 1941 – Kim Jong-il, North Korean leader
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1907 – Giosuè Carducci, Italian writer, Nobel Prize Laureate (b. 1835)
- 1932 – Ferdinand Buisson, French pacifist, Nobel Prize Laureate (b. 1841)
- 1992 – Jânio Quadros, Brazilian politician (b. 1917)
- 1964 – Gabonese president Leon M'ba is toppled by a coup and his rival, Jean-Hilaire Aubame, is installed in his place.
- 2008 – Kosovo declares independence.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1904 – Hans Morgenthau, German political philosopher (d. 1980)
- 1942 – Huey P. Newton, American political activist (d. 1989)
- 1963 – Michael Jordan, American basketball player
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1600 – Giordano Bruno, Italian philosopher (burned at the stake) (b. 1548)
- 1909 – Geronimo, Apache leader (b. 1829)
- 1986 – Jiddu Krishnamurti, Indian philosopher (b. 1895)
Ọjọ́ Kejìdínlógún Oṣù Kejì 18,02: Ọjọ́ ayẹyẹ ìgbòmìnira ní orílẹ̀-èdè Gambia (1965)
- 1929 – àyájọ́ ọjọ́ àkọ́kọ́ tí wọ́n kéde
àmì-ẹ̀yẹ Academy Awards.
- [[]]
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1745 – Àyájọ́ ọjọ́ ìbí Alessandro Volta, tí ó jẹ́ Italian physicist(al. 1827)
- 1931 – Àyájọ́ ọjọ́ ìbí Toni Morrison, olùkọ̀wé ará Amẹ́ríkà (al. 2019)
- 1939 – Àyájọ́ ọjọ́ ìbí Claude Ake, ẹni tí ó jẹ́ onímọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa ètò òṣèlú (Nigerian political scientist) (al. 1996)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 901 – Àyájọ́ ọjọ́ tíThabit ibn Qurra, ẹni tí ó jẹ́ arìnrìn-àjò inú Òṣùpá àti onímọ̀ ìṣirò (Arab astronomer and mathematician) (b. 826)
- 1535 – Àyájọ́ ọjọ́ tí Heinrich Cornelius Agrippa,ẹni tí ó jẹ́ onímọ̀ nípa ipo tí ìràwọ̀ Oju ọ̀run wà àti oniímọ̀ nípa alchemy. 'astrologer and alchemist' (b. 1486)
- 1546 – Àyájọ́ ọjọ́ tí Martin Luther,ẹni tí ó jẹ́ alátúntò ẹ̀sìn ilẹ̀ Jamaní (b. 1483)
- 1986 – The Soviet Union launches its Mir spacecraft. Remaining in orbit for 15 years, it is occupied for 10 of those years.
- [[]]
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1473 – Nicolaus Copernicus, mathematician and astronomer (d. 1543)
- 1940 – Smokey Robinson, American singer
- 1953 – Cristina Fernández de Kirchner, President of Argentina
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1916 – Ernst Mach, Austrian-Czech physicist and philosopher (b. 1838)
- 1962 – Georgios Papanikolaou, Greek doctor, inventor of the Pap smear (b. 1883)
- 1988 – André Frédéric Cournand, French-born physician, Nobel laureate (b. 1895)
- [[]]
- [[]]
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1901 – Muhammad Naguib, President of Egypt (d. 1984)
- 1923 – Forbes Burnham, President of Guyana (d. 1985)
- 1927 - Sidney Poitier, osere ara Amerika.
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1895 - Frederick Douglass (foto), apokoerure ara Amerika (ib. 1818)
- 1907 – Henri Moissan, French chemist, Nobel Prize laureate (b. 1852)
- 1916 – Klas Pontus Arnoldson, Swedish writer and pacifist, recipient of the Nobel Peace Prize (b. 1844)
- 1848 – Karl Marx àti Friedrich Engels tẹ ìwé Manifẹ́stò Kọ́múnístì jáde.
- 1953 – Francis Crick àti James D. Watson ṣe àwárí ìpìlẹ̀ hóró DNA (fọ́tò).
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1921 – John Rawls, amòye ará Amẹ́ríkà (al. 2002)
- 1924 – Robert Mugabe, Ààrẹ ilẹ̀ Zimbabwe
- 1933 - Nina Simone, akọrin ará Amẹ́ríkà (al. 2003).
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1677 – Baruch Spinoza, Dutch philosopher (b. 1632)
- 1926 – Heike Kamerlingh Onnes, Dutch physicist, Nobel Prize laureate (b. 1853)
- 1965 - Malcolm X, Black American civil rights leader (ib. 1925)
Ọjọ́ 22 Oṣù Kejì: Independence Day ni Saint Lucia (1979)
- 1958 – Egypt and Syria join to form the United Arab Republic.
- [[]]
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1732 – George Washington, First President of the United States (d. 1799)
- 1788 – Arthur Schopenhauer, German philosopher (d. 1860)
- 1938 – Ishmael Reed (fọ́tò), American writer
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1512 – Amerigo Vespucci, Italian merchant and explorer (b. 1454)
- 1816 – Adam Ferguson, Scottish philosopher and historian (b. 1723)
- 2002 – Jonas Savimbi, Angolan rebel and political leader (b. 1934)
- 1941 – Plutonium (a button of the metal pictured) was first chemically identified by chemist Glenn T. Seaborg and his team at the University of California, Berkeley.
- [[]]
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1868 - W. E. B. Du Bois (foto), aseoro-awujo ati alakitiyan eto araalu ara Amerika (al.1963)
- 1883 – Karl Jaspers, German philosopher (d. 1969)
- 1924 – Allan McLeod Cormack, South-African born physicist, Nobel laureate (d. 1998)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1855 - Carl Friedrich Gauss, matemático, astrónomo e físico alemão (n. 1777).
- 1990 – José Napoleón Duarte, President of El Salvador (b. 1925)
- 1995 – Melvin Franklin, American singer (The Temptations) (b. 1942)
- 2008 – Fidel Castro retires as the President of Cuba after nearly fifty years.
- [[]]
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1304 – Ibn Battuta, Arabian explorer (d. c.1368)
- 1786 – Wilhelm Grimm, German philologist and folklorist (d. 1859)
- 1866 – Pyotr Nikolaevich Lebedev, Russian physicist (d. 1912)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1810 – Henry Cavendish, English scientist (b. 1756)
- 1876 – Joseph Jenkins Roberts, first President of Liberia (b. 1809)
- 2006 – Octavia Butler, American writer
- [[]]
- [[]]
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1950 – Néstor Kirchner, Argentine politician (d. 2010)
- 1951 – Don Quarrie, Jamaican runner
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1971 – Theodor Svedberg, Swedish chemist, Nobel laureate (b. 1884)
- 1975 – Elijah Muhammad, American Black Muslim leader (b. 1897)
- 1983 – Tennessee Williams, American playwright (b. 1911)
- 1815 – Napoleon Bonaparte sákúrò ní Elba.
- 1952 – Alákóso Àgbà Brítánì Winston Churchill ṣàkéde pé orílẹ̀-èdè òhun ti ní bọ́mbù átọ́mù.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1802 – Victor Hugo (fọ́tò), olùkọ̀wé ará Fránsì (al. 1885)
- 1903 – Giulio Natta, aṣeolóògùn ará Itálíà (al. 1979)
- 1954 – Recep Tayyip Erdoğan, Alákóso Àgbà ilẹ̀ Túrkì
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1931 – Otto Wallach, aṣeolóògùn ará Jẹ́mánì (ib. 1847)
- 1985 – Tjalling Koopmans, aṣeọ̀rọ̀-òkòwò ará Hóllandì (ib. 1910)
- 1998 – Theodore Schultz, aṣeọ̀rọ̀-òkòwò ará Amẹ́ríkà (ib. 1902)
- 1844 – Olómìnira Dómíníkì (àsìá) gba ìlómìnira lọ́dọ̀ Haiti.
- 1933 – Ilé aṣòfin Jẹ́mánì ní Berlin, Reichstag, gbaná jẹ.
- 1999 – Olusegun Obasanjo borí ìdìbòyàn fún ààrẹ Nigeria.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1879 – René Lefebvre, martyr of the French Resistance (d. 1944)
- 1902 – John Steinbeck, American writer, Nobel laureate (d. 1968)
- 1913 – Paul Ricoeur, amòye ará Fránsì (al. 2005)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1943 – Kostis Palamas, Greek poet, twice nominated for the Nobel prize (b. 1859)
- 1989 – Konrad Lorenz, Austrian zoologist, recipient of the Nobel Prize in Physiology or Medicine (b. 1903)
- 1998 – George H. Hitchings, American scientist, recipient of the Nobel Prize in Physiology or Medicine (b. 1905)
- 1922 – The United Kingdom ends its protectorate over Egypt through a Unilateral Declaration of Independence.
- 1928 – C.V. Raman discovered Raman effect.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1915 – Peter Medawar, Brazilian-born scientist, Nobel laureate (d. 1987)
- 1928 – Phillip Nnaemeka-Agu onidajo ara Naijiria (al. 2011)
- 1953 – Paul Krugman, American economist, Nobel laureate
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1916 – Henry James (fọ́tò), American writer (b. 1843)
- 1936 – Charles Nicolle, French bacteriologist, recipient of the Nobel Prize in Physiology or Medicine (b. 1866)
- 1963 – Rajendra Prasad, First President of India (b. 1884)
- 1960 – An earthquake in Morocco kills over 3,000 people and nearly destroys Agadir in the southern part of the country.
- 2004 – Jean-Bertrand Aristide is removed as President of Haiti following a coup.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1896 – Morarji Desai, Prime Minister of India (d. 1995)
- 1960 – Khaled, Algerian raï musician
- 1976 – Ja Rule, American rapper and actor
Àwọn aláìsí lóòní...
- [[]]
- [[]]