Astatínì tabi Astatine je apilese kemika alagbararadio pelu ami-idamo At ati nomba atomu 85. Ohun eyi towuwojulo keji ninu awon halojin. Botilejepe astatini nje mimuwaye nitori ijera alagbararadio ninu adanida, nitori short aabo emi kukuru re a le ri ni iye tintin. Astatini koko je mimuwaye latowo Dale R. Corson, Kenneth Ross MacKenzie, ati Emilio Segrè ni 1940. Odun meta koja ki o to dipe ipase astatini bakanna je wiwari ninu awon alumoni aladanida. Titi di aipe opolopo awon iwuwa aladanida ati kemika astatini je nipa sise afiwe mo awon apilese miran. Melo ninu awon isotopu astatini nje lilo bi olufonsita iwonwo alpha ninu awon imulo sayensi, be sini adanwo awon imulo oniwosan fun astatini 211 ti sele. Lowolowo astatini ni apilese aladanida to sowonjulo pelu idiye bi 30g ni o wa ninu igbele Aye.[2]
Astatínì, 85AtAstatínì |
---|
Pípè | /ˈæstətiːn,_ʔtɪn/ (AS-tə-teen-,_--tin) |
---|
Ìhànsójú | black solid (presumed) |
---|
nọ́mbà ìsújọ | [210] |
---|
Astatínì ní orí tábìlì àyè |
---|
|
Nọ́mbà átọ̀mù (Z) | 85 |
---|
Ẹgbẹ́ | group 17 (halogens) |
---|
Àyè | àyè 6 |
---|
Àdìpọ̀ | Àdìpọ̀-p |
---|
Ẹ̀ka ẹ́límẹ́ntì | Post-transition metal |
---|
Ìtò ẹ̀lẹ́ktrọ́nù | [Xe] 4f14 5d10 6s2 6p5 |
---|
Iye ẹ̀lẹ́ktrọ́nù lórí ìpele kọ̀ọ̀kan | 2, 8, 18, 32, 18, 7 |
---|
Àwọn ohun ìní ara |
---|
Ìfarahàn at STP | solid |
---|
Ìgbà ìyọ́ | 575 K (302 °C, 576 °F) |
---|
Ígbà ìhó | 610 K (337 °C, 639 °F) |
---|
Heat of | 40 kJ/mol |
---|
pressure
P (Pa)
|
1
|
10
|
100
|
1 k
|
10 k
|
100 k
|
at T (K)
|
361
|
392
|
429
|
475
|
531
|
607
|
|
Atomic properties |
---|
Oxidation states | −1, +1, +3, +5, +7[1] |
---|
Electronegativity | Pauling scale: 2.2 |
---|
Covalent radius | 150 pm |
---|
Van der Waals radius | 202 pm |
---|
Other properties |
---|
Natural occurrence | from decay |
---|
Thermal conductivity | 1.7 W/(m·K) |
---|
Magnetic ordering | no data |
---|
CAS Number | 7440-68-8 |
---|
Main isotopes of astatínì |
---|
|
Àdàkọ:Category-inline | references |