Astatínì

(Àtúnjúwe láti Astatine)

Astatínì tabi Astatine je apilese kemika alagbararadio pelu ami-idamo At ati nomba atomu 85. Ohun eyi towuwojulo keji ninu awon halojin. Botilejepe astatini nje mimuwaye nitori ijera alagbararadio ninu adanida, nitori short aabo emi kukuru re a le ri ni iye tintin. Astatini koko je mimuwaye latowo Dale R. Corson, Kenneth Ross MacKenzie, ati Emilio Segrè ni 1940. Odun meta koja ki o to dipe ipase astatini bakanna je wiwari ninu awon alumoni aladanida. Titi di aipe opolopo awon iwuwa aladanida ati kemika astatini je nipa sise afiwe mo awon apilese miran. Melo ninu awon isotopu astatini nje lilo bi olufonsita iwonwo alpha ninu awon imulo sayensi, be sini adanwo awon imulo oniwosan fun astatini 211 ti sele. Lowolowo astatini ni apilese aladanida to sowonjulo pelu idiye bi 30g ni o wa ninu igbele Aye.[2]

Astatínì, 85At
Astatínì
Pípè /ˈæstətn,_ʔtɪn/ (AS--teen-,_--tin)
Ìhànsójúblack solid (presumed)
nọ́mbà ìsújọ[210]
Astatínì ní orí tábìlì àyè
Hydrogen Helium
Lithium Beryllium Boron Carbon Nitrogen Oxygen Fluorine Neon
Sodium Magnesium Aluminium Silicon Phosphorus Sulfur Chlorine Argon
Potassium Calcium Scandium Titanium Vanadium Chromium Manganese Iron Cobalt Nickel Copper Zinc Gallium Germanium Arsenic Selenium Bromine Krypton
Rubidium Strontium Yttrium Zirconium Niobium Molybdenum Technetium Ruthenium Rhodium Palladium Silver Cadmium Indium Tin Antimony Tellurium Iodine Xenon
Caesium Barium Lanthanum Cerium Praseodymium Neodymium Promethium Samarium Europium Gadolinium Terbium Dysprosium Holmium Erbium Thulium Ytterbium Lutetium Hafnium Tantalum Tungsten Rhenium Osmium Iridium Platinum Gold Mercury (element) Thallium Lead Bismuth Polonium Astatine Radon
Francium Radium Actinium Thorium Protactinium Uranium Neptunium Plutonium Americium Curium Berkelium Californium Einsteinium Fermium Mendelevium Nobelium Lawrencium Rutherfordium Dubnium Seaborgium Bohrium Hassium Meitnerium Darmstadtium Roentgenium Copernicium Nihonium Flerovium Moscovium Livermorium Tennessine Oganesson
I

At

Ts
poloniumastatínìradon
Nọ́mbà átọ̀mù (Z)85
Ẹgbẹ́group 17 (halogens)
Àyèàyè 6
Àdìpọ̀Àdìpọ̀-p
Ẹ̀ka ẹ́límẹ́ntì  Post-transition metal
Ìtò ẹ̀lẹ́ktrọ́nù[Xe] 4f14 5d10 6s2 6p5
Iye ẹ̀lẹ́ktrọ́nù lórí ìpele kọ̀ọ̀kan2, 8, 18, 32, 18, 7
Àwọn ohun ìní ara
Ìfarahàn at STPsolid
Ìgbà ìyọ́575 K ​(302 °C, ​576 °F)
Ígbà ìhó610 K ​(337 °C, ​639 °F)
Heat of 40 kJ/mol
 pressure
P (Pa) 1 10 100 1 k 10 k 100 k
at T (K) 361 392 429 475 531 607
Atomic properties
Oxidation states−1, +1, +3, +5, +7[1]
ElectronegativityPauling scale: 2.2
Covalent radius150 pm
Van der Waals radius202 pm
Other properties
Natural occurrencefrom decay
Thermal conductivity1.7 W/(m·K)
Magnetic orderingno data
CAS Number7440-68-8
Main isotopes of astatínì
Iso­tope Abun­dance Half-life (t1/2) Decay mode Pro­duct
210At syn 8.1 h ε, β+ 3.981 210Po
α 5.631 206Bi
211At syn 7.2 h
Àdàkọ:Category-inline
| references

Itumosi àtúnṣe

  1. Àdàkọ:Greenwood&Earnshaw2nd
  2. Close, Frank. Particle Physics: A Very Short Introduction. Oxford University Press: New York, 2004. Page 2.