Fránsíọ̀m

(Àtúnjúwe láti Francium)

Fránsíọ̀m tabi Francium, mimo tele bi eka-caesium ati actinium K,[akiyesi 1] je apilese kemika to ni ami-idamo Fr ati nomba atomu 87. O ni ikan ninu awon odionina tokerejulo larin gbogbo awon apilese ti a mo, bakanna ohun ni apilese aladanida keji tosowonjulo (leyin astatine). Fransiom je onide to je radioalagbara giga to n jera si astatine, radium, ati radon. Gege bi onide alkali, o ni agbara elektroni kan.

Francium, 87Fr
Francium
Pípè /ˈfrænsiəm/ (FRAN-see-əm)
Ìhànsójúmetallic
nọ́mbà ìsújọ[223]
Francium ní orí tábìlì àyè
Hydrogen Helium
Lithium Beryllium Boron Carbon Nitrogen Oxygen Fluorine Neon
Sodium Magnesium Aluminium Silicon Phosphorus Sulfur Chlorine Argon
Potassium Calcium Scandium Titanium Vanadium Chromium Manganese Iron Cobalt Nickel Copper Zinc Gallium Germanium Arsenic Selenium Bromine Krypton
Rubidium Strontium Yttrium Zirconium Niobium Molybdenum Technetium Ruthenium Rhodium Palladium Silver Cadmium Indium Tin Antimony Tellurium Iodine Xenon
Caesium Barium Lanthanum Cerium Praseodymium Neodymium Promethium Samarium Europium Gadolinium Terbium Dysprosium Holmium Erbium Thulium Ytterbium Lutetium Hafnium Tantalum Tungsten Rhenium Osmium Iridium Platinum Gold Mercury (element) Thallium Lead Bismuth Polonium Astatine Radon
Francium Radium Actinium Thorium Protactinium Uranium Neptunium Plutonium Americium Curium Berkelium Californium Einsteinium Fermium Mendelevium Nobelium Lawrencium Rutherfordium Dubnium Seaborgium Bohrium Hassium Meitnerium Darmstadtium Roentgenium Copernicium Nihonium Flerovium Moscovium Livermorium Tennessine Oganesson
Cs

Fr

Uue
radonfranciumradium
Nọ́mbà átọ̀mù (Z)87
Ẹgbẹ́group 1: H and alkali metals
Àyèàyè 7
Àdìpọ̀Àdìpọ̀-s
Ẹ̀ka ẹ́límẹ́ntì  Alkali metal
Ìtò ẹ̀lẹ́ktrọ́nù[Rn] 7s1
Iye ẹ̀lẹ́ktrọ́nù lórí ìpele kọ̀ọ̀kan2, 8, 18, 32, 18, 8, 1
Àwọn ohun ìní ara
Ìfarahàn at STPsolid
Ìgbà ìyọ́? 300 K ​(? 27 °C, ​? 80 °F)
Ígbà ìhó? 950 K ​(? 677 °C, ​? 1250 °F)
Kíki (near r.t.)1.87 g/cm3
Heat of fusionca. 2 kJ/mol
Heat of ca. 65 kJ/mol
 pressure (extrapolated)
P (Pa) 1 10 100 1 k 10 k 100 k
at T (K) 404 454 519 608 738 946
Atomic properties
Oxidation states+1 Àdàkọ:Infobox element/symbol-to-oxidation-state/comment
ElectronegativityPauling scale: 0.7
Covalent radius260 pm
Van der Waals radius348 pm
Other properties
Natural occurrencefrom decay
Crystal structure ​(bcc)
Cubic body-centered crystal structure for francium
Thermal conductivity15 W/(m·K)
Electrical resistivity3 µ Ω·m
Magnetic orderingParamagnetic
CAS Number7440-73-5
Main isotopes of francium
Iso­tope Abun­dance Half-life (t1/2) Decay mode Pro­duct
221Fr syn 4.8 min α 6.457 217At
222Fr syn 14.2 min β 2.033 222Ra
223Fr trace 22.00 min β 1.149 223Ra
α 5.430 219At
Àdàkọ:Category-inline
| references

Francium je wiwari latowo Marguerite Perey ni Fransi (nibi ti apilese yi ti ri oruko) ni 1939. Ohun ni apilese togbeyin ti o je wiwari ninu adanida, kanran jije sisopapo.[akiyesi 2] Lode yara ise-idanwo, francium sowon gidigidi, iye ipase je wiwari ninu alumoni aladalu uranium ati thorium, nibi ti isotopu francium-223 ti n je didasile to si n je jijera bibaun. Iye to kere bi 20–30 g (ounce kan) lowa nigba yiowu kakiri inu igbele Aye; awon isotopu yioku je alasopapo yanyan. Iye titobijulo ti o je kikojo lai isotopu yiowu ni isupo bi awon atomu 10,000 (ti francium-210) ti won je didasaye gege bi efuufu tutugidi ni Stony Brook ni 1997.[1]


Awon akiyesile

àtúnṣe
  1. Actually the least unstable isotope, francium-223
  2. Awon apilese alasopapo, bi technetium, ti je wiwari ninu adanida.
  1. CRC Handbook of Chemistry and Physics. 4. CRC. 2006. p. 12. ISBN 0-8493-0474-1.