Klorínì ( /ˈklɔəriːn/ KLOHR-een; lati Èdè Grííkì Ayéijọ́un: χλωρóς [khlôros] error: {{lang}}: text has italic markup (help) "pale green") je elimenti kemika to ni nomba atomu 17 ati ami-idamo Cl. Ohun ni halojínì keji to fuyejulo, leyin fluorini to je eyi to fuyejulo. Klorini wa ninu tabili alakoko ninu adipo 17. Apilese yi le di horo oniatomumeji labe awon isele opagun, ti a n pe ni klorinimeji (dichlorine). O ni ibasepo elektroni to gajulo ati ijealodionina keta to gajulo larin gbogbo awon apilese; fun idi eyi klorini je oxidizing agent to lagbara.
Klorínì, 17Cl |
Klorínì |
---|
Pípè | /ˈklɔːriːn,_ʔaɪn/ (KLOR-een-,_---yn) |
---|
Ìhànsójú | pale yellow-green gas |
---|
Ìwúwo átọ̀mù Ar, std(Cl) | [35.446, 35.457] conventional: 35.45 |
---|
Klorínì ní orí tábìlì àyè |
---|
|
Nọ́mbà átọ̀mù (Z) | 17 |
---|
Ẹgbẹ́ | group 17 (halogens) |
---|
Àyè | àyè 3 |
---|
Àdìpọ̀ | Àdìpọ̀-p |
---|
Ẹ̀ka ẹ́límẹ́ntì | Reactive nonmetal |
---|
Ìtò ẹ̀lẹ́ktrọ́nù | [Ne] 3s2 3p5 |
---|
Iye ẹ̀lẹ́ktrọ́nù lórí ìpele kọ̀ọ̀kan | 2, 8, 7 |
---|
Àwọn ohun ìní ara |
---|
Ìfarahàn at STP | ẹ̀fúùfù |
---|
Ìgbà ìyọ́ | 171.6 K (-101.5 °C, -150.7 °F) |
---|
Ígbà ìhó | 239.11 K (-34.04 °C, -29.27 °F) |
---|
Kíki (at STP) | 3.2 g/L |
---|
Critical point | 416.9 K, 7.991 MPa |
---|
Heat of fusion | (Cl2) 6.406 kJ/mol |
---|
Heat of | (Cl2) 20.41 kJ/mol |
---|
Molar heat capacity | (Cl2) 33.949 J/(mol·K) |
---|
pressure
P (Pa)
|
1
|
10
|
100
|
1 k
|
10 k
|
100 k
|
at T (K)
|
128
|
139
|
153
|
170
|
197
|
239
|
|
Atomic properties |
---|
Oxidation states | −1, +1, +2, +3, +4, +5, +6, +7 Àdàkọ:Infobox element/symbol-to-oxidation-state/comment |
---|
Electronegativity | Pauling scale: 3.16 |
---|
energies | |
---|
Covalent radius | 102±4 pm |
---|
Van der Waals radius | 175 pm |
---|
Spectral lines of klorínì |
Other properties |
---|
Natural occurrence | primordial |
---|
Crystal structure | orthorhombic |
---|
Speed of sound | (gas, 0 °C) 206 m/s |
---|
Thermal conductivity | 8.9x10-3 W/(m·K) |
---|
Electrical resistivity | > 10 Ω·m (at 20 °C) |
---|
Magnetic ordering | diamagnetic[1] |
---|
CAS Number | 7782-50-5 |
---|
Main isotopes of klorínì |
---|
|
Àdàkọ:Category-inline | references |