Àtòjọ àwọn olórin ilẹ̀ Nàìjíríà
ojúewé àtojọ Wikimedia
Èyí ni àtòjọ àwọn olórin tó gbajúmọ̀ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Àwọn tí wọ́n jẹ́ ìlú mọ̀ọ́ká nìkan ni a kó jọ sí abẹ́ ààtò yí. Ẹ lè wo àtòjọ ìpín àwọn orin orílẹ̀ èdè náà ní ẹ̀ka 'Nigerian musical groups'.
0-9
àtúnṣe- 2face Idibia - Olórin hip hop àti R&B
- 9ice - Olórin hip hop àti afropop
A
àtúnṣe- A-Q - Àwọn olórin hip hop ni:
- Eedris Abdulkareem
- Afrikan Boy - ̀olórin Ráàpù
- Afro Candy - olórin Pọ́ọ̀pù
- Tọ́pẹ́ Àlàbí - olórin Ẹ̀mí
- Yẹmí Àlàdé- olórin R&B àti Pọ́ọ̀pù
- Tony Allen
- Eva Alordiah - olórin Ráàpù
- Amarachi
- Aramide sarumoh- olórin Afro àti Jáàsì
- Àṣá- olórin R&B àti Pọ́ọ̀pù,Orílẹ̀ àti Olùkọrin
- Cobhams Asuquo - olórin Sóòlù (soul)
- Alhaji Àlàmú Tátalọ̀ - olórin ìbílẹ̀
- Yinka Ayefele- olórin Gospel
- Adéwálé Àyúbà - olórin Fújì
B
àtúnṣe- Ayinde Bakare
- Banky W - olórin R&B àti Pọ́ọ̀pù,Orílẹ̀ àti Olùkọrin
- Adé Bantu
- Korede Bello - olórin R&B àti Pọ́ọ̀pù,Orílẹ̀ àti Olùkọrin àti onílù
- TY Bello - olórin Gospel
- Blackface- olórin Régè
- Andre Blaze - olórin Ráàpù
- Brymo
- Burna Boy - olórin àlùjó Régè
C
àtúnṣeD
àtúnṣe- D'banj - olórin Pọ́ọ̀pù
- Da Emperor - olórin Ráàpù ti ìbílè
- Da Grin - olórin Ráàpù Yorùbá
- Daddy Showkey
- I.K. Dairo
- Timi Dakolo - olórin tí ó gba àmì ẹ̀yẹ ti Idol West Africa (2007)
- Stella Damasus - olórin Sóòlù (soul) àti R&B
- Dammy Krane
- Darey - olórin R&B àti Olùkọrin
- Davido - olórin Pọ́ọ̀pù
- Yinka Davies - olórin Jáàsì
- Oliver De Coque
- Safin De Coque - Olórin hip hop àti Ráàpù
- Dekumzy - olórin R&B àti Highlife
- Dice Ailes
- Di'Ja
- Tonto Dikeh - olórin Pọ́ọ̀pù
- Don Jazzy - olórin tí ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde
- D'Prince - olórin Afro àti Pọ́ọ̀pù
- Dr. Alban
- Dr SID - olórin Pọ́ọ̀pù
- Duncan Mighty - olórin Régè
E
àtúnṣe- Frank Edwards - olórin gospel
- Omotola Jalade Ekeinde - olórin R&B àti Pọ́ọ̀pù
- eLDee - olórin Ráàpù, Olùkọrin ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde
- Emma Nyra - olórin R&B
- Emmy Gee - olórin Ráàpù
- Alhaji Dauda Epo-Àkàrà - Àwúrèbe
F
àtúnṣe- Falz - olórin Ráàpù àti Olùkọrin
- Majek Fashek - olórin R&B àti Olùkọrinàti Olùkọrin
- Faze - olórin R&B
- Flavour N'abania - olórin Pọ́ọ̀pù àti Highlife
G
àtúnṣe- Tonye Garrick - olórin R&B àti Olùkọrin
- Adekunle Gold - olórin àti Olùkọrin
- Ruby Gyang
H
àtúnṣe- Harrysong - olórin àti Olùkọrin
- Humblesmith -olórin Afro àti Pọ́ọ̀pù
I
àtúnṣe- Ice Prince - olórin Ráàpù
- Haruna Ishola - olórin Àpàlà
- Helen Parker-Jayne Isibor - olórin àti Olùkọrin
- Ifedayo Olarinde
- Iyanya - pop singer
J
àtúnṣe- Jesse Jagz - olórin Ráàpù
- Joe el
- Johnny Drille
- Tamara Jones - olórin R&B àti Olùkọrin
K
àtúnṣe- Kcee
- Kefee
- Peter King
- Tunde King
- King Wadada - olórin Régè
- Kizz Daniel
- Koker
- Korede Bello
- Ayinla Kollington
- Abiodun Koya Wọn bi ní (1980),olórin gospel, àti opera
- Fela Kuti - olórin jaasi, afrobeat, onílù àti Olùkọrin
- Femi Kuti - olórin jaasi, afrobeat, onílù àti Olùkọrin
- Seun Kuti - olórin jaasi, afrobeat, onílù àti Olùkọrin
L
àtúnṣe- Lagbaja olórin àti onílù Bàtá
- Lara George - olórin gospel
- Rex Lawson
- Lil Kesh
M
àtúnṣe- Mayorkun
- M.I - olórin Ráàpù
- M Trill -olórin Ráàpù
- J. Martins - olórin tí ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde
- May7ven
- Prince Nico Mbarga
- Maud Meyer - olórin jáàsì
- Mike Ejeagha - olórin Highlife
- Mo'Cheddah -olórin Pọ́ọ̀pù
- Mode 9 - olórin Ráàpù
- Cynthia Morgan - olórin Pọ́ọ̀pù àti dacehall
- Mr 2Kay
- Mr Raw
- Muma Gee - olórin Pọ́ọ̀pù àti Olùkọrin
- Muna - olórin Ráàpù
- Muraina Oyelami
N
àtúnṣe- Naeto C
- Nathaniel Bassey
- Tunde Nightingale
- Niniola - Afro-house artist
- Niyola - olórin jáàsì ati sóòlù
- Genevieve Nnaji - olórin Pọ́ọ̀pù
- Nneka - olórin Pọ́ọ̀pù ati sóòlù
- Nosa - olórin gospel
O
àtúnṣe- Alhaji Abass Akande Obesere -olórin fújì
- Ebenezer Obey- olórin jùjú
- Obiwon - olórin R&B àti gospel
- Monica Ogah - olórin Pọ́ọ̀pù àti Olùkọrin
- Ego Ogbaro
- Dele Ojo - olórin Jùjú àti Olùkọrin
- Sonny Okosuns -olórin Highlife àti Olùkọrin
- Pericoma Okoye
- Sammie Okposo - olórin gospel
- Victor Olaiya - Olùkọrin
- Olamide - olórin Pọ́ọ̀pù àti Ráàpù
- Babátúndé Ọlátúnjí
- Yusuf Ọlátúnjí - olórin Àpàlà
- Omawumi - olórin sóòlù (soul)
- Onyeka Onwenu - olórin Pọ́ọ̀pù
- William Onyeabor
- Orezi - olórin régè
- Oriental Brothers
- Oritse Femi
- Osita Osadebe
- Orlando Owoh olórin highlife
- Òjó Adé - olórin gospel
- Oxlade
- Patience Ozokwor -olórin highlife
P
àtúnṣe- Patoranking - olórin régè àti dancehall
- Pepenazi - olórin Ráàpù, Pọ́ọ̀pù, Olùkọrin ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde
- Peruzzi
- Shina Peters - olórin Afro-Jùjú
- Phyno - olórin Ráàpù ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde
- Praiz - olórin R&B àti Olùkọrin
R
àtúnṣe- Reekado banks - olórin Pọ́ọ̀pù
- Rema
- Reminisce
- Ruggedman - olórin Pọ́ọ̀pù àti Ráàpù
- Runtown - olórin Pọ́ọ̀pù àti Olùkọrin
S
àtúnṣe- Sade Adu - olórin R&B àti sóòlù (soul)
- Salawa Abeni - olórin Wákà
- Samsong - olórin gospel
- Sasha P- olórin Ráàpù
- Seyi Shay Shay - olórin Pọ́ọ̀pù àti Olùkọrin
- Sean Tizzle - olórin Afro-Pọ́ọ̀pù
- Simi
- Sinach - olórin gospel
- Skales - olórin Ráàpù
- Slimcase
- Sound Sultan - olórin Ráàpù
- Fela Sowande
- Sunny Ade - olórin jùjú
T
àtúnṣe- Tekno Miles - olórin Afro-Pọ́ọ̀pùolórin R&B àti Olùkọrin
- Terry G - olórin R&B, Olùkọrin ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde
- Timaya - olórin régè
- Tiwa Savage - olórin R&B àti Olùkọrin
- Tony Tetuila-olórin R&B àti Olùkọrin
U
àtúnṣe- Sir Victor Uwaifo - olórin highlife
W
àtúnṣeY
àtúnṣe- YCEE - olórin Ráàpù
- Yemi Blaq
- Yung6ix - olórin Ráàpù
Z
àtúnṣeẸ̀ tún lè wo
àtúnṣe- Music of Nigeria