Fẹ́rmíọ̀m tabi Fermium (pípè /ˈfɜrmiəm/, FER-mee-əm) je apilese aladipapo pelu ami-idamo Fm ati nomba atomu 100. Gege bi apilese teyinuraniom onide alagbraradio giga ti eseese aktinidi, fermium nje dida nipa ddigbolu plutonium pelu awon neutroni o si je sisoloruko fun Enrico Fermi onimofisiyiki inuatomu. Fermium ni apilese teyinuraniom kejo.

Fermium
100Fm
Er

Fm

(Upn)
einsteiniumfermiummendelevium
Ìhànsójú
unknown, probably silvery, white or metallic gray
Àwọn ìdámọ́ wíwọ́pọ̀
Orúkọ, àmì-ìdámọ́, nọ́mbà fermium, Fm, 100
Ẹ̀ka ẹ́límẹ̀nti actinide
Ẹgbẹ́, àsìkò, àdìpò n/a7, f
Ìwúwo átọ́mù (257)
Ìtòléra ẹ̀lẹ́ktrónì [Rn] 5f12 7s2
2, 8, 18, 32, 30, 8, 2
Physical properties
Phase solid
Melting point 1800 K, 1527 °C, 2781 °F
Atomic properties
Oxidation states 2, 3
Electronegativity 1.3 (Pauling scale)
Ionization energies 1st: 627 kJ·mol−1
Miscellanea
CAS registry number 7440-72-4
Àwọn ísótòpù dídúró jùlọ
Main article: Àwọn ísótòpù fermium
iso NA half-life DM DE (MeV) DP
252Fm syn 25.39 h SF - -
α 7.153 248Cf
253Fm syn 3 d ε 0.333 253Es
α 7.197 249Cf
255Fm syn 20.07 h SF - -
α 7.241 251Cf
257Fm syn 100.5 d α 6.864 253Cf
SF - -
· r


ItokasiÀtúnṣe