Tábìlì àyè àwọn ẹ́límẹ̀ntì
Tábìlì àyè àwọn ẹ́límẹ̀ntì je ona eleto agbehan awon apilese egbo. Bo tile je pe iru tabili yi ti wa tele, eni ti gbogbo eniyan gba pe o da ni onimo khemistry Ararussia Dimitri Mandeleev ni odun 1869. Mandeleev fe tabili yi lati s'afihan ("igba") isele bi a se n da awon apilese mo. Atunse ti bo si iyasile tabili yi, be ni o si ti fe si bi a ba se n seawari awon apilese tuntun be sini a ti se iko apere elero (theoretical model) tuntun la ti se alaye iwuwa egbo.[1]
Tabili igba ti je pataki nisinyi ninu imo eko Khemistry, nipa lati pin si owoowo, la si ona to mogbon wa ati lati safiwe awon orisirisi iru iwa egbo. Be na sini tabili yi n je lilo ninu eko Fisiki, Biology, imoero ati Ileise ero. Tabili ise (standard) isinyi ni 117 apilese ti a le fihan gege bi January 27, 2008 (nigbati apilese 118 ti je imudipo (synthesized) apilese 117 ko ti je be).
Ilanaoye ti a fi n sagbekale tabili igba
àtúnṣeTabili igba ise (Standard periodic table)
àtúnṣeGroup → | 1 | 2 | 3 | 4 | 5 | 6 | 7 | 8 | 9 | 10 | 11 | 12 | 13 | 14 | 15 | 16 | 17 | 18 | ||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
↓ Period | ||||||||||||||||||||
1 | 1 H |
2 He | ||||||||||||||||||
2 | 3 Li |
4 Be |
5 B |
6 C |
7 N |
8 O |
9 F |
10 Ne | ||||||||||||
3 | 11 Na |
12 Mg |
13 Al |
14 Si |
15 P |
16 S |
17 Cl |
18 Ar | ||||||||||||
4 | 19 K |
20 Ca |
21 Sc |
22 Ti |
23 V |
24 Cr |
25 Mn |
26 Fe |
27 Co |
28 Ni |
29 Cu |
30 Zn |
31 Ga |
32 Ge |
33 As |
34 Se |
35 Br |
36 Kr | ||
5 | 37 Rb |
38 Sr |
39 Y |
40 Zr |
41 Nb |
42 Mo |
43 Tc |
44 Ru |
45 Rh |
46 Pd |
47 Ag |
48 Cd |
49 In |
50 Sn |
51 Sb |
52 Te |
53 I |
54 Xe | ||
6 | 55 Cs |
56 Ba |
* |
72 Hf |
73 Ta |
74 W |
75 Re |
76 Os |
77 Ir |
78 Pt |
79 Au |
80 Hg |
81 Tl |
82 Pb |
83 Bi |
84 Po |
85 At |
86 Rn | ||
7 | 87 Fr |
88 Ra |
** |
104 Rf |
105 Db |
106 Sg |
107 Bh |
108 Hs |
109 Mt |
110 Ds |
111 Rg |
112 Uub |
113 Uut |
114 Uuq |
115 Uup |
116 Uuh |
117 Uus |
118 Uuo | ||
* Lanthanides | 57 La |
58 Ce |
59 Pr |
60 Nd |
61 Pm |
62 Sm |
63 Eu |
64 Gd |
65 Tb |
66 Dy |
67 Ho |
68 Er |
69 Tm |
70 Yb |
71 Lu | |||||
** Actinides | 89 Ac |
90 Th |
91 Pa |
92 U |
93 Np |
94 Pu |
95 Am |
96 Cm |
97 Bk |
98 Cf |
99 Es |
100 Fm |
101 Md |
102 No |
103 Lr |
Notes
- Lanthanides are also known as "rare earth elements", a deprecated term. Regarding group membership of these elements, see here.
- Alkali metals, alkaline earth metals, transition metals, actinides, lanthanides, and poor metals are all collectively known as "metals".
- Halogens and noble gases are also non-metals.
|
|
Alternative versions (Layout/view of the table)
àtúnṣe- Iru tabili ise bi ti oke yi je apere ipile.
- Iru tabili anaro ti a le yi lo sile fun ojuewe to fun
- Iru tabili gbangba fun wa ni ipile ati oruko awon apilese lekunrere
- Iru tabili totobi fun ni awon toke pelu iposi atomu awon apilese
- Iru tabili lekunrere
- Iru tabili agbara imunawa
- Iru Tábìlì ìgbà (iseto atanna)
- Iru Tábìlì ìgbà (irin ati aije-irin)
Atosile
àtúnṣeIyasile tabili igba n safihan (igba) isele fun idamo awon egbo. A se akojo awon apilese bi nomba atomu won se n po si (eyun àkọ́wá ati inuikun atomu). Lori ila kanna ni awon apilese ti won ni idamo kanna wa ("akojopo")
Itokasi
àtúnṣe- Theodore L. Brown, H. Eugene LeMay, and Bruce E. Bursten (2005). Chemistry:The Central Science (10th edition ed.). Prentice Hall. ISBN 0-13-109686-9.
- Helmenstine, Marie (2007). "Trends in the Periodic Table". About, Inc. Retrieved 2007-01-27.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |