Imí ọjọ́ tabí Sulfur ( sulphur ní èdè Brítènì) ni ó jẹ́ kẹ́míkà tí a ma ń ṣe àdámọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú àmì S tí númbà rẹ̀ jẹ́ 16. Imí ọjọ́ jẹ́ ìkan nínú àwọn kẹ́míkà tí tí ó pọ̀ jùlọ ní orílẹ̀ àgbáyé. Àpapọ̀ imí ọjọ́ ati átọ́mù ni ó lábẹ́ oru tí kò lágbára ni ó ma ń yíra padà sí cyclic octatomic molecules tí ètò ìyípadà rẹ̀ ń jẹ́ S8. Àwọn kẹ́míkà tí wọ́n kórajọ di imí ọjọ́ ni wọ́n ma ń ní àwọ̀ oòrùn rẹ́súrẹ́su tí ó sì ma ń le koko nígbà tí ó bá wà ní abẹ́ ilé tí kò sí Oòrùn.

Súlfúrù, 16S
Súlfúrù
Ìhànsójúlemon yellow sintered microcrystals
Ìwúwo átọ̀mù Ar, std(S)[32.05932.076] conventional: 32.06
Súlfúrù ní orí tábìlì àyè
Hydrogen Helium
Lithium Beryllium Boron Carbon Nitrogen Oxygen Fluorine Neon
Sodium Magnesium Aluminium Silicon Phosphorus Sulfur Chlorine Argon
Potassium Calcium Scandium Titanium Vanadium Chromium Manganese Iron Cobalt Nickel Copper Zinc Gallium Germanium Arsenic Selenium Bromine Krypton
Rubidium Strontium Yttrium Zirconium Niobium Molybdenum Technetium Ruthenium Rhodium Palladium Silver Cadmium Indium Tin Antimony Tellurium Iodine Xenon
Caesium Barium Lanthanum Cerium Praseodymium Neodymium Promethium Samarium Europium Gadolinium Terbium Dysprosium Holmium Erbium Thulium Ytterbium Lutetium Hafnium Tantalum Tungsten Rhenium Osmium Iridium Platinum Gold Mercury (element) Thallium Lead Bismuth Polonium Astatine Radon
Francium Radium Actinium Thorium Protactinium Uranium Neptunium Plutonium Americium Curium Berkelium Californium Einsteinium Fermium Mendelevium Nobelium Lawrencium Rutherfordium Dubnium Seaborgium Bohrium Hassium Meitnerium Darmstadtium Roentgenium Copernicium Nihonium Flerovium Moscovium Livermorium Tennessine Oganesson
O

S

Se
fósfórùsúlfúrùklorínì
Nọ́mbà átọ̀mù (Z)16
Ẹgbẹ́group 16 (chalcogens)
Àyèàyè 3
Àdìpọ̀Àdìpọ̀-p
Ẹ̀ka ẹ́límẹ́ntì  Reactive nonmetal
Ìtò ẹ̀lẹ́ktrọ́nù[Ne] 3s2 3p4
Iye ẹ̀lẹ́ktrọ́nù lórí ìpele kọ̀ọ̀kan2, 8, 6
Àwọn ohun ìní ara
Ìfarahàn at STPaláralíle
Ìgbà ìyọ́388.36 K ​(115.21 °C, ​239.38 °F)
Ígbà ìhó717.8 K ​(444.6 °C, ​832.3 °F)
Kíki (near r.t.)(alpha) 2.07 g/cm3
(beta) 1.96 g/cm3
(gamma) 1.92 g/cm3
when liquid (at m.p.)1.819 g/cm3
Critical point1314 K, 20.7 MPa
Heat of fusion(mono) 1.727 kJ/mol
Heat of (mono) 45 kJ/mol
Molar heat capacity22.75 J/(mol·K)
 pressure
P (Pa) 1 10 100 1 k 10 k 100 k
at T (K) 375 408 449 508 591 717
Atomic properties
Oxidation states−2, −1, 0, +1, +2, +3, +4, +5, +6 Àdàkọ:Infobox element/symbol-to-oxidation-state/comment
ElectronegativityPauling scale: 2.58
energies
Covalent radius105±3 pm
Van der Waals radius180 pm
Color lines in a spectral range
Color lines in a spectral range
Spectral lines of súlfúrù
Other properties
Natural occurrenceprimordial
Crystal structureorthorhombic
Orthorhombic crystal structure for súlfúrù
Thermal conductivity(amorphous)
0.205 W/(m·K)
Electrical resistivity(amorphous)
2×1015  Ω·m (at 20 °C)
Magnetic orderingdiamagnetic[1]
Bulk modulus7.7 GPa
Mohs hardness2.0
CAS Number7704-34-9
History
DiscoveryChinese[2] (Before 2000BC)
Recognized as an element byAntoine Lavoisier (1777)
Main isotopes of súlfúrù
Iso­tope Abun­dance Half-life (t1/2) Decay mode Pro­duct
32S 95.02% 32S is stable with 16 neutrons
33S 0.75% 33S is stable with 17 neutrons
34S 4.21% 34S is stable with 18 neutrons
35S syn 87.32 d β 0.167 35Cl
36S 0.02% 36S is stable with 20 neutrons
Àdàkọ:Category-inline
| references

Imí ọjọ́ jẹ́ ìkan lára àwọn kẹ́míkà mẹ́wá tí ó pọ̀ jùlọ lágbàáyé tí ó sì jẹ́ ẹlẹ́karùn un tí ó pọ̀ jùlọ ní orí ilẹ̀ ayé. Wọ́n ma ń rí imí ọjọ́ ní ọ̀pọ̀ yanturu ní orí ilẹ̀ agbáyé, wọ́n sì dá a mọ̀ ní ayé atijọ́ ní àwa ìlú bíi China, , India àti Greece tí ó fi mọ́ Egypt gẹ́gẹ́ bí ohun èlò gidi fún ìlera wọn. Nínú ìtàn, wọ́n ṣe akọsílẹ̀ oríṣiríṣi ní imí ọjọ́ nínú ìmọ̀ lítíréṣọ̀ tí wọ́n sì fun ní orúkọ brimstone,[3] which means "burning stone".[4]

Láyé òde òní, orísiríṣi ohun èlò ni wọ́n ń fi imí ọjọ́ ṣe lẹ́yìn tí wọ́n bá ti yọ àwọn èròjà alágbára tí ó léwu kúrò nínú rẹ̀. [5][6]

Wọ́n ń lo imí ọjọ́ fún ìpèsè àwọn orísiríṣi nkan bíi ajílẹ̀, sulfuric acid ati àwọn nkan miran. Wọ́n m ń lo imí ọjọ́ nínú ìmọ̀ ìṣirò, wọ́n ń lòó láti fi pèsè oògùn ẹ̀fọn ati àwọn àwọn oògùn apakòkòrò míràn. Púpọ̀ nínú àwọn èròjà inú imí ọjọ́ ni wọ́n ní òórùn, nígbà tí àwọn òórun wọn jẹ́ àdámọ́ wọn, àwọn òórùn bíi òórùn omi ọsàn, ata ilẹ̀. Ìdí ni wípé àwọn èròjà wọ̀nyí jẹ́ àdámọ́ rẹ̀. Èyí tí ó jẹ́ Hydrogen sulfide ni ó ma ń mú òórùn bí ẹyin tí ó ti di òbu jáde látàrí àdámọ́ rẹ̀.

Imí ọjọ́ jẹ́ ohun pàtàkì fún gbogbo ohun abẹ̀mí.

Ìrísí ati àbùdá rẹ̀ àtúnṣe

 
gẹ́gẹ́ bí ohun líle, imí ọjọ́ ní abùdá àwọ̀ òrùn rẹ́súrẹ́sú bíi ti ọsàn wẹ́wẹ́. Nígbà tí a bá sun un níná, yóò pupa bí ẹ̀jẹ̀ tí yóò sì ma yọ eruku búlúù


Àwọn itọ́kasí àtúnṣe

  1. Magnetic susceptibility of the elements and inorganic compounds, in Handbook of Chemistry and Physics. CRC press. 2000. ISBN 0849304814. http://www-d0.fnal.gov/hardware/cal/lvps_info/engineering/elementmagn.pdf. 
  2. "Sulfur History". Georgiagulfsulfur.com. Retrieved 2008-09-12. 
  3. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Greenwd
  4. Àdàkọ:Cite EB1911
  5. Laurence Knight (Jul 19, 2014). "Sulphur surplus: Up to our necks in a diabolical element". BBC. 
  6. "Sulfur". Elements. BBC. Oct 11, 2014. . Download here.